Asa - Awé Lyrics
Get the lyrics to the song: Awé by Asa at LyricsKeeper.com.
Awé
Awé Lyrics |
---|
What Are The Lyrics For Awé By Asa?
Awe I bo lo lo ka
Ta n fi wao ka Ibi o ba lo je a mo Anti to n gbe le I to si O wa o wa le yi Ati o jo meta atabo O wi kpe o, o O loyun fun o Oyun oshu meji Oloyun fun o Wahidi omo sekina Omo muyina Omo mohammed Anti ton loyun fun o O to bi e l'omo I wo iwo na Anti to loyun fun o O to bi e l'omo, o bi 'mo oh oh O bi 'mo Ire lo ni mu, ese Irun ori,iwo dudu Omo kpu pa ba wo lo se ri Wahidi omo sekina Omo muyina Omo mohammed Ewa wo ja la a fin Oba ejigbo atabo, atako Wan ja la fin oba La fin oba. Wahidi omo muyina ni Omo sekina O foju mi ri mabo Mabo ni le,mabo loko mabo l'eko Mama to bi mama re Ni mama mi, emi na bi te mi Moo ntomo lowo f'omo loyon Ma ko tire bami Abo oro lan so f'omo Luabi To ba de nu re a do n di n di Din din |
Who Wrote Awé By Asa?
Bukola Elemide, Cobhams Emmanuel Asuquo
|
What's The Duration Of The Awé By Asa?The duration of Awé is 5:15 minutes and seconds. |
More Lyrics
0 | 1 | 2 | 3 | 4 | 5 | 6 | 7 | 8 | 9 | A | B | C | D | E | F | G | H | I | J | K | L | M | N | O | P | Q | R | S | T | U | V | W | X | Y | Z
Lyrics Of The Day
- M.A.M: Oh Gott Lieber Gott, sag', kannst du mich jetzt retten…
- Mark Feltham: Lady Luck There's a woman in New Orleans…
- M.I.R.V.: Cool I wish I was cool…
- Wah!: The Story of the Blues, Pt. 1 Here in my pocket…
- Wylde Ratttz: T.V. Eye Lord…